WELCOME, TITILADE OLAGOKE, TO THE NITI EXAM HALL
Please identify yourself and do a translation of the two texts below.
You have a maximum of 100 MINUTES beginning from now. Good luck.
You have a maximum of 100 MINUTES beginning from now. Good luck.
SOURCE TEXT 1 - English - YorubaEducation with tears
In 1939, I told my father that I wanted to go to school simply because I admired Psalm 19 which a friend of mine who was a pupil could recite by heart. I admired particularly, the first two and the last verses which read thus: (1) The heavens are telling the glory of God and the firmament proclaims his handiwork (2) day by day pours forth speech and night to night declares knowledge. The last verse reads; “Let the words of my mouth and the meditation of my heart be acceptable in thy sight O Lord my Rock and my Redeemer”. These verses in Yoruba language worked like magic on me and made me to act spontaneously by immediately approaching my father to allow me to go to school to learn how to read and write. At that time even though a pupil needed to become a Christian, my father instantly approved my request; unlike his response to my earlier request when he refused to let me become a Muslim. He immediately approached a literate cousin, the late Mr. Theophilus Akinbola Akande for advice. Mr. Akande agreed to help and he told me that he would like me to go to St. Mary’s African Church School Ileogbo where his friend Mr. Daniel Durojaye was the headmaster. I started to attend school from the third quarter of the year 1939. Later someone in our compound advised my father to withdraw me from the school as I was the only young boy left to go to the farm with him. The man said that my father would henceforth be responsible for drawing water fetching firewood and cooking as well as pounding yam. I was happy that my father said that he could not go against my wish. There and then I became the house boy to this cousin. I fetched firewood drew water and did all kinds of other domestic chores. |
|
SOURCE TEXT 2 - Yoruba - English
Ẹ jọwọ, ẹ ka itan yii ki ẹ si tumọ rẹ si ede gẹẹsi.
IBẹRẹ AYọ
Aye ni olukọ n jẹ loko lootọ. Mo bẹẹrẹ isẹ olukọ l’oko kan ti a n pe l’Afọlabi Obideyi ni ijọba ibilẹ Akanran. Nigba ti mo de ‘bẹ, mo ba olukọ marun-un. Baba l’Owode ni mo mọ orukọ ọga wa si, sugbọn Sango ni agekuru orukọ rẹ. Sango le, o ga, o sigbọnlẹ. oju rẹ le kokoko bi oju arọ. O mu siga ju loko lọ. Emi gan-an alara ko si kẹrẹ. Bi Sango ba yọ lọna oke atiwọ ile-iwe, eefin siga ni bi igba ti ọkọ oju irin ba n g’oke. Emi Arẹmu naa a si yọ lọna isalẹ pẹlu eefin to da bii t’ọkọ Aja dudu taa ti lo f’ọdun mẹwaa. Abọọgbọ, baye ba yẹni tan, iwa ibajẹ lo ku, ọga n mu siga, olukọ n mu. A n jiya a ni a n yọ l’oko tisa. Aago kan l’a n siwọ isẹ. Bo ba ti daago mọkanla abọ, ẹlẹmu a wa, eyun-un baba alagbẹdẹ, a ti gb’ẹmu wa ka wa mọ ‘le iwe. Ariya bẹẹrẹ niyen. Ife Sango lo tobi to si ninu ju. Ngbọ? Sebi oun lọga! Awọn obirin inu wa ko gbẹyin, ọrẹ wa, iya ibeji n mu gbọ-ọn ẹmu. Bo ba m’ẹmu yo tan, a bẹẹrẹ ọrọ. A ni, “Iya n jẹ ’niyan. Iru awọn Arẹmu wọnyi ko tii lalaa a n waye ti mo ti bẹẹrẹ isẹ olukọ.” S’emi naa a si ti m’ẹmu diẹ, maa dahun maa ni, mọmọ bawo lo ti wa jẹ?